Download PDF
Back to stories list

Kíka àwọn ẹranko Counting animals

Written by Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek

Illustrated by Rob Owen

Translated by Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán

Language Yoruba

Level Level 1

Narrate full story The audio for this story is currently not available.


Erin kan fẹ́ lẹ mu omi.

One elephant is going to drink water.


Àgùfọn méjì fẹ́ lọ mu omi.

Two giraffes are going to drink water.


Ẹfọ̀n mẹ́ta àti ẹyẹ mẹ́rin fẹ́ lọ mu omi.

Three buffaloes and four birds are also going to drink water.


Ẹtu márùnún àti túrùkú mẹ́fà ń rìn lọ sí ibi omi.

Five impalas and six warthogs are walking to the water.


Sẹ́bírà méje ń sáré lọ mu omi.

Seven zebras are running to the water.


Kọ̀ǹkọ̀ mẹ́jọ àti ẹja mẹ́sànàn ń wẹ̀ nínú omi.

Eight frogs and nine fish are swimming in the water.


Kìnìún kan bú ramúramù.Òun náà fẹ́ mu omi Tani ń bẹ̀rù kìnìún?

One lion roars. He also wants to drink. Who is afraid of the lion?


Erin kan ń mu omi pẹ̀lú kìnìún.

One elephant is drinking water with the lion.


Written by: Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Illustrated by: Rob Owen
Translated by: Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
Language: Yoruba
Level: Level 1
Source: Counting animals from African Storybook
Creative Commons License
This work is licensed under a Creative Commons Attribution 3.0 International License.
Options
Back to stories list Download PDF